Connect with us


Gospel

Tope Alabi – Yes And Amen [Video+Lyrics]

Published

on

Download Tope Alabi - Yes And Amen

Renowned indigenous singer, Tope Alabi, has graced her fans with an enchanting melody titled “Yes And Amen,” extracted from her remarkable 2018 album of the same name.

The album, “Yes And Amen,” stands as a testament to Tope Alabi’s consistent ability to captivate her dedicated fanbase. The track “Yes And Amen” is a standout piece within this project, offering a captivating musical experience that listeners shouldn’t miss.

Tope Alabi’s musical prowess is not limited to her gospel genre; she has also made significant contributions to the Yoruba movie industry through her impactful soundtracks. Her music has transcended borders, earning her admirers from various corners of the globe. Today, she stands tall as one of Nigeria’s most cherished gospel singers.

Watch the video below;

Yes And Amen Lyrics

Amin Ase ida a lamo oEni ti o ni a padanuIba o to to olu Imo oEni ti o ni o, ko ni nkankan oAmin asedaEni ti o ni o, ko ni nkankan oEni ti o ni o, ko ni nkankan(Ko ni nkankan)Eni ti o ni o, ko ni nkankan oOoooooooEni ti o ni o, ko ni nkankanE ko ni nkankan o
Mo wa ri foba to ni di da aiye eeeeIbare mare e, oni gbede orunIwo to ni gbogbo aiye ni ikawoBo ti doyi katoIba oni mo to ga ju eeBaba ni baba seAmin ase ida mo gbe ba funAmin ase ida la mo oEni ti o ni o keEni ti o ni a padanuAdanu nla lo pa laye, lorunIba o toto olu imoA ton ton to, mo ri ba, mori ba oEni ti o ni o ko ni nkankanKo ni nkankanEni ti o ni o ko ni nkankan oE ma ni penre laboEni ti o ni o, ko ni nkankanKo ni kini nkan lagbonEni ti o ni o, ko ni nkankan oO tan fun laiye lorun oEni ti o ni o Ee
Ko ni nkankan
O da okun, O da oosaAlara to fi omi se oshoIwo to mo ibi eja gba do odoMajemu to bu ko ja okunIyanrin te ka aiyeO da okunkun biri muOga imole ooOju orun o ni ilekun ooOgbe bi mejeeji, lai rin irin ajoO mu eda gba inu eda waiyeIbi emi ngba lo ba, eni kan o moAjulo o eni ti o wa o
Ko le mo nkankanEni ti o wa ke o
Eni ti o ni o, ko ni nkankan oKo ri nkankan o oEni ti o ni o, ko ni nkankanAfoju san ju oni to hun lo mo gbaEni ti o ni o, ko ni nkankan
EeEni ti o ni o, ko ni nkankan
Eee
Majemu alai lepin n lo jeIjinle alaile tun woIrawo nyo lailai lo nka beniOsupa nse atokun to ba dale beni oIbi gbogbo la n ti mi ri beniO to lo fara da orun saiye beni oO se ojo otun so da eran beniOsuwon bi oye, otun sotutu beni oEranko Igbo won lo su a beniEweko, ewebe igi iyen o se sawa ri naEni ti o ri se e, ko ri nkankan oEni ti o ri se e, ko ri nkanEni ti o ri se e, ko ri nkankanKo da ko ri ra e pa be niEni ti o ri se e, ko ri nkankan oOooEni ti o ri se e, ko ri nkankan…
Beat…
Ose mi da bi ohun, opin mi ni ipinTi ko Jo ti eni kejiMi o la le hu, emi ni ami aseda latorunAdagbeyin ni mi o wa fi mi jobaOhun gbogbo ti o ti ko daOdami ofunmi ni reEmi ni beeni, ase olodumare niAmin lohun, emi lamiAyanmo ogo, Ogun mi niEda emi lo fi se ranse miAkori Iran mi, oju ogo re ni
Mo ni imi ye re ninuEni o ri mi, ko ri nkankanEee Eni ti o ri miKo ri nkankan.
Eni ti o ri miKo rise olorun woE Eni ti o ri mi ke, ko ri nkanEni ti o ri miKo ri nkankan oE o fojuEni ti o ri mi, ko rise olorun wo
Ko ri olodumare, oda mi bi ohun niEni ti o ri mi, ko ri nkankan
Eni ti o ri mi, ko ri se olorun woOooooooEni ti o ri mi, ko ri nkankan o
Eni ti o ri mi, ko ri se olorun woEni ti o ri mi ko ri nkankan
Ami lawa je, si Iwo aminBeni ire loje ki aiye wa o
Olorun la minAmin lon famin wa hanAiye, atorun lamin yen oAseda ni aminOro re lo je ki a ma waOlorun la min
Amin, Amin, Amin, Amin o
Translate to English

Fenton is a talented and experienced news and entertainment writer at TopNaija, passionate about sharing stories that matter. With a keen eye for detail and a talent for crafting engaging and compelling content, he has built a strong reputation as a reliable and insightful writer. Fenton is a dedicated and talented writer committed to producing high-quality content that is informative, entertaining, and engaging.

Trending