Connect with us


Gospel

Aye Ope Yo – Adeyinka Alaseyori

Published

on

Aye Ope Yo – Adeyinka Alaseyori-TopNaija.ng
E se Aye ope yoE se toripe aye ope yoE se Aye ope yo oEmi awon woli oAye ope pada yo
Gbogbo ale ta sun ta ji, aye ope kan niGbogbo igba ta ba sun lale,Ta o ranti lati Gbadura, e o gba ki ile wo pa wa lat’oju orun wa sayeAimoye igba ta ma ji, ta ma ma sare pe a ti late Otun d’abo bo wa oO f’aye gba satani lati yo ayo isegun lori aye waAye ope pada yoL’ati ile loti mu wa o mu wa joko pelu awon omo aladeO f’aye gba wa laarin awon omo alade ilu waA wa n’soro nibi gigaMo ki o toripe aye ope yo oEmi awon woli oAye ope pada yoMelo leebu awon eyan lara wa, to gbon danu Pelu eriMelo ni awa to ti rope,Ohun rere o le ti Inu wa jade,To funrugbin ohun rere sinu wa to Tun jeyoMo ki o toripe aye ope yo oAfter all we’ve been throughAye ope pada yoIgba kan ri won da’so fun o ko to di pe awon Omo to bi ri aso wo ni oIgba kan ri won da’so fun o ko to di peAwon Omo to bi ninu re r’aso bo ihoho wonIgba kan ri o pelu awon ton gbe kiriLati ma toro Owo loju titi ese oloore toripeAye ope pada yoAhAye ope yoO se aye ope yoO se Aye ope yo oEmi awon woli oAye ope pada yo
Igba ti o si nkankan se pe aye ope le yoIgba ti gbogbo ohun gbogbo doju ru se pe aye Ope tun le yoKi la o ni dupe fun nigbati aye ope ti yo oAfter all we’ve been throughAye ope pada yoIgba kan ri won pe o l’agan oSugbon lowolowo o pada gbomo joIgba kan ri won sa fun o lawujo awon eyan gidiSugbon lowolowo o ti joko pelu awon ololaIgba kan ri oo won ti write e off pe ohun rere o le Tinu reJade wa, won ti write e off pe ohun rere o Le tinu re jade waSugbon emi Inu awon woli,Agbanilagbatan Agbani ma gbowo,Arugbo ojo jojo ninu eni to Fun ojo loju lati ma yoNinu re ni ojo tin je ojo o, ojo to yo ninu re lo JoOju ton riran ninu okunkun birimu birimuEni nla ton se ohun nlaEni nla ton se ohun ari tokasiEyan a ma gbe oyun sinu, fun gbogbo osu mesan, iwo na ni abo wonEni aye de oyun mo ninu fun odun meji,Meeta, meerin, maarun, meefa logan to ba o padeO tu won sile lai gba ohunkohun raraEmi awon woli oO se o, toripe aye ope pada yoAimoye oloyun to yo ninu ewuAimoye trailer to subu Lu motorO je a si lara wonA o gbe ounje pari, a le mai si nibi toye Ka waSugbon a dupe ibi te ba wa deKinihun eya Judah aye ope pada yoOhun gbogbo lo se fun miOhun gbogbo lo se fun miKi lo ti se fun mi ko si oOhun gbogbo lo se fun miO fun mi lomo bi o se oO fun mi loko fe o se oIwo to gbe mi jade lati inu iraTo fo mi laso moIwo to pin okun pupa niya lai se peOmi ya lu Awon omo isreali lojo yenBawo lo se se, iwo ni o kabiyesi olola, iwo na niOhun gbogbo lo se fun miOhun gbogbo lo se fun miKi lo ti se fun mi ko si oOhun gbogbo lo se fun miGbogbo ojo lon d’abo bo mi lon yo mi ninu ewuLara ohun to se fun mi ti mi o le soNi emi ti mon Mi sinu to o gba lowo miLara ohun to se fun mi ti mi o le so tan ni oju Iriran,Ese ton rin, owo ton sise,Eti ton gboran, Speaker to soro jade ninu mi o be oOhun gbogbo ma lo se ninu ohun gbogboAimoye ijakadi lile to ja lori oro mi loru mojuIwo lo se, iwo lo je ohun gbogbo ninu ohun Gbogbo,Atobi tan o, atoba tan, a to Baba ma pe Enikeni ni BabaIwo ni o o oOro tin gbe’nu Omo eniyan f’ohunOro ton gbe inu ikoko tu asiri won ni gbangbaOju to ri okunkun ninu okunkun oOju to la okunkun loju ninu okunkun birimu Birimu, iwo na niBaba mi o o oA dun f’oro lo, a to ba soro, a to f’ise ogun ran,A to Baba ma pe Enikeni ni Baba,Aridunnu mi nigba Ti ibanuje de,Owo ton gba ibi kuro loju ona Wa, iwo ma ni, iwo ma ni oIwo ni, iwo ma ni oIwo ni Baba mi o, iwo ni ore miBawo lo se seTi igi fi koja lo sinu omi to magnet irin wa sori Omi,Aake to jabo sinu omi lojo yen igi loFi gbe jade, owo airi re lon sise agbara oOwo airi re lo se wonder lojo yenIwo ni, iwo ma niBawo lo se seObinrin onisun eje laarin egbegberun
Overview

Lyrics

Listen

Videos

Artists

Main results

E se Aye ope yoE se toripe aye ope yoE se Aye ope yo oEmi awon woli oAye ope pada yo
Gbogbo ale ta sun ta ji, aye ope kan niGbogbo igba ta ba sun lale,Ta o ranti lati Gbadura, e o gba ki ile wo pa wa lat’oju orun wa sayeAimoye igba ta ma ji, ta ma ma sare pe a ti late Otun d’abo bo wa oO f’aye gba satani lati yo ayo isegun lori aye waAye ope pada yoL’ati ile loti mu wa o mu wa joko pelu awon omo aladeO f’aye gba wa laarin awon omo alade ilu waA wa n’soro nibi gigaMo ki o toripe aye ope yo oEmi awon woli oAye ope pada yoMelo leebu awon eyan lara wa, to gbon danu Pelu eriMelo ni awa to ti rope,Ohun rere o le ti Inu wa jade,To funrugbin ohun rere sinu wa to Tun jeyoMo ki o toripe aye ope yo oAfter all we’ve been throughAye ope pada yoIgba kan ri won da’so fun o ko to di pe awon Omo to bi ri aso wo ni oIgba kan ri won da’so fun o ko to di peAwon Omo to bi ninu re r’aso bo ihoho wonIgba kan ri o pelu awon ton gbe kiriLati ma toro Owo loju titi ese oloore toripeAye ope pada yoAhAye ope yoO se aye ope yoO se Aye ope yo oEmi awon woli oAye ope pada yo
Igba ti o si nkankan se pe aye ope le yoIgba ti gbogbo ohun gbogbo doju ru se pe aye Ope tun le yoKi la o ni dupe fun nigbati aye ope ti yo oAfter all we’ve been throughAye ope pada yoIgba kan ri won pe o l’agan oSugbon lowolowo o pada gbomo joIgba kan ri won sa fun o lawujo awon eyan gidiSugbon lowolowo o ti joko pelu awon ololaIgba kan ri oo won ti write e off pe ohun rere o le Tinu reJade wa, won ti write e off pe ohun rere o Le tinu re jade waSugbon emi Inu awon woli,Agbanilagbatan Agbani ma gbowo,Arugbo ojo jojo ninu eni to Fun ojo loju lati ma yoNinu re ni ojo tin je ojo o, ojo to yo ninu re lo JoOju ton riran ninu okunkun birimu birimuEni nla ton se ohun nlaEni nla ton se ohun ari tokasiEyan a ma gbe oyun sinu, fun gbogbo osu mesan, iwo na ni abo wonEni aye de oyun mo ninu fun odun meji,Meeta, meerin, maarun, meefa logan to ba o padeO tu won sile lai gba ohunkohun raraEmi awon woli oO se o, toripe aye ope pada yoAimoye oloyun to yo ninu ewuAimoye trailer to subu Lu motorO je a si lara wonA o gbe ounje pari, a le mai si nibi toye Ka waSugbon a dupe ibi te ba wa deKinihun eya Judah aye ope pada yoOhun gbogbo lo se fun miOhun gbogbo lo se fun miKi lo ti se fun mi ko si oOhun gbogbo lo se fun miO fun mi lomo bi o se oO fun mi loko fe o se oIwo to gbe mi jade lati inu iraTo fo mi laso moIwo to pin okun pupa niya lai se peOmi ya lu Awon omo isreali lojo yenBawo lo se se, iwo ni o kabiyesi olola, iwo na niOhun gbogbo lo se fun miOhun gbogbo lo se fun miKi lo ti se fun mi ko si oOhun gbogbo lo se fun miGbogbo ojo lon d’abo bo mi lon yo mi ninu ewuLara ohun to se fun mi ti mi o le soNi emi ti mon Mi sinu to o gba lowo miLara ohun to se fun mi ti mi o le so tan ni oju Iriran,Ese ton rin, owo ton sise,Eti ton gboran, Speaker to soro jade ninu mi o be oOhun gbogbo ma lo se ninu ohun gbogboAimoye ijakadi lile to ja lori oro mi loru mojuIwo lo se, iwo lo je ohun gbogbo ninu ohun Gbogbo,Atobi tan o, atoba tan, a to Baba ma pe Enikeni ni BabaIwo ni o o oOro tin gbe’nu Omo eniyan f’ohunOro ton gbe inu ikoko tu asiri won ni gbangbaOju to ri okunkun ninu okunkun oOju to la okunkun loju ninu okunkun birimu Birimu, iwo na niBaba mi o o oA dun f’oro lo, a to ba soro, a to f’ise ogun ran,A to Baba ma pe Enikeni ni Baba,Aridunnu mi nigba Ti ibanuje de,Owo ton gba ibi kuro loju ona Wa, iwo ma ni, iwo ma ni oIwo ni, iwo ma ni oIwo ni Baba mi o, iwo ni ore miBawo lo se seTi igi fi koja lo sinu omi to magnet irin wa sori Omi,Aake to jabo sinu omi lojo yen igi loFi gbe jade, owo airi re lon sise agbara oOwo airi re lo se wonder lojo yenIwo ni, iwo ma niBawo lo se seObinrin onisun eje laarin egbegberunEniyan ton Lon, ase jade Lara re Logan lo mo oO koja lo sorisun isun eje odun mejila, loba gbe Lesekese o,Awon oni dokita ati babalawo won ti Gba, gbogbo eyan ti gba,Woli ika ti gba, real woli Ti gba,Sugbon Logan ti o ba o pade lo rowo AgabaraBawo lo se seIwo ni, iwo lo yeOdi Jericho, o subu pelu ariwo leekan soosoBawo lo se seAwon omo isreali rin l’aginju fun odidiOgoji Odun, bata won o je, aso won o gboIwo ni asiri ton so won di tuntun lojojumoBawo lo se se o kabiyesi ololaBawo lo se se oni wonder ton gbe wonder mi oIyanu ton ya aye lenu, bawo lo se seOni wonder oni wonder o se oEmimimo bawo lo se seTi iyo kekere fi trace arin omi,Ko disappear to fi De orisun isale odo mara,O so di didun, o so di Didun, o so odo mara di didunOni wonder oni wonder o seJesu oni wonder o se oJesu oni wonder o se oJesu oni wonder o seunEru ton d’eru b’eru oEru t’eru ri to sa t’eru o le ba oErujeje ton d’eru b’eru oEru re ba mi olodu to mo gbogbo are patapataIna loju, ina lenuGbogbo ara kikida aseIbi to ba de l’ase duro siIbi to ba si iyanu o ki le sele oNinu re ni aragba yamuyamu iyanu ngbe ti oLe Tan, orisun iyanu, orisun ara, inu re niOni wonder oni wonder o seJesu oni wonder o se oJesu oni wonder o se oJesu oni wonder o se oIwo l’ariwo to ta laarin awon egungun gbigbeIwo lo so egungun gbigbe di aye ti ori wa orunRi Ti orun wa ara won ri ti won o miss ara wonIwo l’asiri ton gba yitiyiti ninu osumareAsiri ta wa ta o ri, iwo na niE ru, oba eru, oba eruEru re to ba oE ru, oba eru, oba eruEru re to ba oEru ton d’eru b’eruEru t’eru o le ba oErujeje t’eru o le ba oEru re to ba oE ru, oba eru, oba eruEru re to ba oEni ti gbogbo aye binu si, wa ma yonu siEru ni oEni ti gbogbo aye pada leyin re, wa ma fa moraEru ni oEni ti gbogbo aye nda lebi, wa ma da won lareEru ni oE ruEru re to mi ba oE ru, oba eru, oba eruEru re to ba oE ru, oba eru, oba eruEru re to ba oGbogbo eda to ti write off, wa ma si new Chapter fun wonEru re to mi ba oE ru, oba eruEru re to mi ba o
Advertisement

Trending