Music
Adeyinka Alaseyori – Arojinle (Oni Duro Mi Ese O)
AROJINLE (Oni Duro Mi Ese O) by Adeyinka Alaseyori is a powerful song of worship from the deep thought of gratitude and appreciation to God Almighty for so many things He has done for us.
“Oni Duro Mi Ese O” (my guarantor, I’m grateful) is a part of the song which started at exactly 7mins 45secs into the song.
A Worship Medley that was cut out from the place of devotion and prayers.
Arojinle (Oni Duro Mi Ese O) is an intense worship song that reveals the numerous goodness of God to mankind, many of which we take lightly or look at as insignificant.
Listen, download, and enjoy!
DOWNLOAD Arojinle (Oni Duro Mi Ese O) By Adeyinka Alaseyori
Lyrics for Arojinle (Oni Duro Mi Ese O) By Adeyinka Alaseyori
Mo regbe mi ton shala lakitan
Mo regbe mi tin won dawopo fun jeun lorita
Mo regbe mi taye ti ya no were o
Emi o seni yin o baba
Aika Moye egbe mi, tin won o le da seun kohun fun rawon
Emi to fun loju, fun lowo fun ni gbogbo eya ara, gbogbo re Sa ni mo wa dupe fun
Omo o ku momi lowo Oko o momi Lori mowa lalafia o
Emi o seni yin o baba
Mo ro arojinle Lori aye mi o
Ibi anu bayemi de o Arojinle no mo ro
Mo roooooo arotunro o
Lati igba ti o si nkankan to fi gbemi de bi mo de
Igba taye sope otitan ti wo Olorun so ni gbangban pe oku
Awon ileku taye sope awon ti ti
Ti wo olurun sope osi
Emi ro arotunwo mo ro arojinle oo
Ibi anu bayemi de o
Arojinle ni mo ro
Gbogbo igba tin mo n wo moto mo n bole layo
Kin se gbogbo eniyan to n wo moto lodele won pada o
Awa tan n Jade nile ta n bale lalafia eje a dupe
Awa tOlorun o gba kibi o kogun sile ejaka gbega
Ai moye egbe wa to n be ni mortuary
Aika moye egbe wa ti won ti rale fun ni graveyard o
Iwo tOlorun dasi to n yo ninu ewu lojojumo o je gbega o
Aanu ni morigba o o aanu sa lo ri o o ooo
Moro arojinle lori aye mi o
Ibi aanu baye mi de o, arojinle ni mo ro
Igba kan ri mo pelu awon to n toro aso wo
Igba kan ri a pelu awon ti ko le da jeun funrawa
Igba kan apelu awon to n bebe koto dipe adahun rere se o
Ewo bi aanu ran wa lowo de o
Ewo bi aanu mu wa lowo dani de mu wa rinrin ogo to jagu
Eja a dupe lowo Olorun oba
Oke talagbara gun to n mi ele
Oke talagbara gun to n mi ele
Ohun lemi omore gun ti mofayo wa dupe
Oke ti alagbara gun to n mi ele
Odun to koja talagbara lo taye gbomo pa lowo won eh
Oro talagbara so ti won o fi laju saye mo o
Aso talagbara kan wo ti won jo eni tan wa lati pa
Ohun talagbara se todipe won won bewo wo lositu deni eleni oje dupe
Iwo to lafani lati ma se bo se wu e ninu olala Olorun oje dupe
Iwo to n jeun lasiko to n momi lasiko o je dupe daada lowo Olorun
Aika moye awon eniyan ti won fegba fun lounje je kakiri
Eh aika moye awon eniyan to n fegba sope kan losun to n sope kan lo ji
Oke ti alagbara gun to n mi ele
Emi wo mo wo, emi wo mo wo
Emi wo o, mo wo yika
Mori pope ye baba
Ose fun aanu to ga ti mo ri
Ose fun iranlowo ti o legbe ti o fi bami rinrin ajo yi o
Iba je eyan lo n da bobo bo gbogbo wa ni a o ba ti sesin
Iba je eyan lo n bo asiri wa won o ba ti ja wa si wowo ni gbangba
Olorun ti o gba kaye tu aso lara wa lojiji e ja jo ki o
Olorun ti o gba kaye gbomo pa lowo wa e ja sowipe o se o
Olorun ton mu wa dubule lalafia to mu wa soji lalafia o
Ipa wa ko agbarawa ko
Olorun lo n gbe aye duro
Base n lo, base nbo irorun loba de
Iwo to kuro nile to ba ile lalafia o je dupe dada lowo Olorun
Aika moye eniyan to dagbere nile to je pe nigba to n ma pada dele Ile ti darowo
Ati omo ati oko ati aya ati oun ini won gbogbo re lo jo mole
Iwo ti Olorun da si ni level by levels o je dupe lowo Olorun o
Alabo nibi ti ko si abo
Oluranlowo wa lojo ogun le
Ipa! to te aye wa siwaju ni gba toye kayewa ma lole Asiri wa to bo Iwo ni
Agbara to n fun wa ni idahun ebe adura wa ni Koko oun so di testimony ni gbangba iwo lope ye
Emi Inu awon woli okan awon ajiyin rere o
Ogo ogo ogo ogo ogo ni foruko re o
Ai moye awon oloju meji to n soda titi to moto n pa
Iwo to loju meji to n soda layo Olorun lo mu wa lowo dani soda
Kin se ipa wa kin se agbara wa
Abo Olorun lo daju lori wa o
Eje Jo ki o, eja Jo gbega
Oni duro mi e seun o
Agbejoro mi ema seun o
Bo jeniyan lo n duro ni wa ti ma soro
Bo jeniyan lo n duro ni wa ti salo
Bo jeniyan lo n duro ni wa ti ma siregun
Oni duro me e seun o
Kin se mimo se
Kin se agbara mi
kin se titobi mi o, le se dami si o baba
Asiri to n gba yiti ninu osumare a gbe o ga
Eni kerin ninu Ina ileru
Ogo to wonu ofo eniyan to n mogo Jade o
Ogo to kale sinu eniti o je ofo , to je korofo to mu ogo ja gbangba
Owo!
owo eniti o se agbara to n sise iyanu nla o
Ohun enit’ oun fa igi gbe to n fagi kedari ya
Ina saju re losi ogun ojo gbogbo awon ota re run o
Iwo to pase pe ki Ina Jo, lori igbe ti igbe ko si run
Iwo to pase kina ma Jo lori igbe ti igbe kosi run o
Owo nla ipa nla
Algbara nla
Oloruko aperire
Ina loju ina lenu
Eni kerin ninu Ina ileru o
Ayeraye ninu eni ti aye toro aye lati ma je ayeraye
Orogun gbo gun je, orogun gbogun mi
Orogun na’gun legba o
Kiniun nla to n fa kiniun aye gbogbo le nu ya
Oba to pase awe fawon kiniun ninu Iwo kiniun loje yen o
Leyin awe olojo meta to pase fawon kiniun
Obo won pelu awon ota danieli tile tile won
Olorun nla oloruko nla oloruko apekore oloruko aperire
Akoda aseda ameda
Gbani gbani ti aye saya
Ope lamuwa iyin lamuwa
Ounje yin la gbe wa kin se nipa iwa mimo
Kin se nipa iwa mimo, Kin se nipa iwa mimo
Mo wa dupe ore atodun mo dun
Mowa dupe ore atosomo su o
Mo wa dupe ore igba gbogbo
Emi na re oluwa
Irin ajo oju ala awon omo wa Iwo lo o gba kiwon toju orun de oju iku
Ala lile t’awon omo wa la
Iwo ni o gba kaye pa won loju orun
Awa ta n ji saye lojojumo, kin se agbara wa kin se ipa wa
Kin se gbogbo eniyan to sun lale lo n ji
Awa tOlorun ji saye e ja sope o se
Aika moye awon te Jo wo labor room lojo to bimo to